Ìyá kogberegbe, ní gbogbo ara àdúgbò mọ ó si, àmọ́ ìyá èkó ni àwọn ẹbí ń pè é. Kii dá rìn lai si ìyá Dupẹ.…
Mo ti pàdé ọ̀pọ̀ ènìyàn ní ìwọ̀n ọdún tí mo tì lò láyé, sùgbọ́n sàsà ni èyí tí ó nípa bíi bàbá Àmọ̀pé. Ọkùnrin mẹ́ta…
Ẹ̀rọ Omi Báwo ni ó máa ń rí l’ára nígbà tí o bá ń gbìyànjú àti gba ẹlòmíràn là tí ìwọgan an wá di ẹni…