Jòjòló akéwì tún dé Mo fẹ́ kọrin ewì sétí aráyé Ẹ yá mi létí yín. Ọ̀rọ̀ fẹ́ máa jábọ́ bí odi ẹyìn. Kí ẹ sáré…
Orin: Ẹnikẹ́ni tí ìwọ bá nípa láti se ìrànlọ́wọ́ fún Òun náà lẹni kejì rẹ, tọ́jú rẹ. Ẹnikẹ́ni tó bá nípa láti ṣe ìrànwọ́ fún…
Ìbínú kò mọ̀ pé olówó òun ò lẹ́sẹ̀ ńlẹ̀. Ọ̀rẹ́ wa kan ló fi àṣejù kó bá ara rẹ̀ lẹ́nu ọjọ́ mẹ́ta yìí. Ó ń…