ỌJÀ LAYÉ ỌJÀ LAYÉ Ọjà layé ọ̀rẹ́ mìi, Ọjà layé ará. Gbogbo ọmọ adáríhunrun pátá lówá nájà láyé, Dandan sì ni ká padà s'ílé e…
Ìdùnnú a ṣubú lu ayọ̀ Lọ́jọ́ a bá bímọ tuntun sáyé Tẹbítará a kí túńfúlù káàbọ̀. Bọ́jọ́ ṣe ń gorí ọjọ́ Tóṣù ń gorí oṣù…
Ọdún Ọlọ́jọ́ jẹ́ ọdún tó wuyì tó sì ṣe pàtàkì ní ilé-ifẹ̀, ọdọọdún ni wọ́n máa ń ṣe ọdún yìí. Ọdún Ọlọ́jọ́ yìí ló tóbí…
Mi ò rántí ìgbà tí mo kọ́kọ́ gbọ́ gbólóhùn “Ọlọ́jọ́” nínú ọ̀rọ̀, àmọ́ mo rántí wípé nígbà èwe mi, tí àwọn èèyàn bá sọ wípé,…