Àṣàyàn OlóòtúỌ̀rọ̀ OlóòtúỌ̀rọ̀ Láti Ọ̀dọ̀ Olóòtú — Ìpalẹ̀mọ́ Pọ̀pọ̀ṣìnṣìn ỌdúnAtelewoNovember 17, 2022November 17, 2022 by AtelewoNovember 17, 2022November 17, 20220232 Ẹ̀yin Ònkàwé, Ẹ kú u dédé àsìkò yìí o ẹ̀yin òǹkàwé wa, a sì kú ìpalẹ̀mọ́ pọ̀pọ̀ṣìnṣìn odún tuntun tó... Read more
Aáyan ògbufọ̀ìtan Arìnrìn-àjò Kan | Olúwáfẹ́mi Kẹ́hìndé LawrenceAtelewoNovember 13, 2022November 13, 2022 by AtelewoNovember 13, 2022November 13, 2022018 Ìtan Arìnrìn-àjò kan/ The Child’s story Ìtan Arìnrìn-àjò kan Ní àkókò kan ṣẹ́yìn, ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọdún tí ó dára ṣẹ́yìn.... Read more
Àpilẹ̀kọÌtàn ÀròsọÒtítọ́ Lérè | Ọláyàtọ̀ ỌláolúwaAtelewoNovember 8, 2022 by AtelewoNovember 8, 2022029 Ní ìlú kan tí à ń pè ní Bíkú, Bí-ikú-ilé-ò-pa-ni ni àjápè orúkọ ìlú yìí ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn fẹ́ràn... Read more
EwìÀyájọ́ Falẹ! | Bákàrè Wahab TáíwòAtelewoNovember 8, 2022November 8, 2022 by AtelewoNovember 8, 2022November 8, 2022023 Àyàjọ́ Falẹ! À ń gbòròmọdiẹ lọ́wọ́ ikú Tonídìí ní í dà nígbẹ̀yìn bídìí bàjẹ́ Ó tún ti ṣẹ̀ bó ti... Read more
EwìÌwé Le! | Wahab Bákàrè TáíwòAtelewoNovember 8, 2022November 8, 2022 by AtelewoNovember 8, 2022November 8, 2022022 Ìwé Le! Túlẹ̀, ẹ sáré wá Akẹ́kọ̀ọ́, ẹ wá gbọ́ nàsíà Òkun kì í hó ruru Ká wà á ruru,... Read more
EwìAgbẹ́kẹ̀lé Ènìyàn | Bákàrè Wahab TáíwòAtelewoNovember 8, 2022November 8, 2022 by AtelewoNovember 8, 2022November 8, 2022022 Agbẹ́kẹ̀lé Ènìyàn Mo gbọ́ pé ayé wà Mo múra èrò ìjìnlẹ̀ Mo rí i pẹ́dàá ń ráyé lò Mo múra,... Read more
EwìOkùn Ìfẹ́ Yi! | Bákàrè Wahab TáíwòAtelewoNovember 8, 2022November 8, 2022 by AtelewoNovember 8, 2022November 8, 2022023 Okùn Ìfẹ́ Yi! Ìfẹ́ pọ́gbọ̀n, ó jọgbọ̀n Ìfẹ̀ pégba, ó jugba Ìfẹ́ pérínwó, ó jurínwó Ìfẹ́ẹ̀fẹ́ táyé fẹ́lá lóko Kò... Read more