ÀTẸ́LẸWỌ́ PÉLÉBÉ
Tí àwọn ònkọ̀wé mejìdínlógójì bá parapọ̀ láti kọ lórí àṣà, àgbègbè, òṣèlú, ìwòsàn, ènìyàn, ìwà, ìfẹ́, àbò, ẹwà abbl ǹkan tó yẹ a màá retí ní ìwé Atẹlẹwọ Pélébé – àkójọpọ̀ èrò ní èdè Yorùbá.
Iyé = 500 Naira
Ó wà lori OKADABOOKS.
Ẹ sì tún le ra PDF ìwé naa dàrẹẹtì lọwọ wa ti à ó sì sẹ́ndì rẹ̀ sí méélì yín tabi WhatsApp.
Ẹ tiransifa àpò méjì àbọ̀ (N500) si àkántì yìí:
Orúkọ Bánkì: First Bank (Savings)
Nómbà Àkántì: 3047635789
Ẹ Sẹ́ndì arídájú tiransifa naa sí [email protected] tàbí 07061282516 (WhatsApp) à ó sì sẹ́ndì kọ́pì yín ní kía kía.