EwìÌwé Le! | Wahab Bákàrè TáíwòAtelewoNovember 8, 2022November 8, 2022 by AtelewoNovember 8, 2022November 8, 2022022 Ìwé Le! Túlẹ̀, ẹ sáré wá Akẹ́kọ̀ọ́, ẹ wá gbọ́ nàsíà Òkun kì í hó ruru Ká wà á ruru,... Read more
EwìAgbẹ́kẹ̀lé Ènìyàn | Bákàrè Wahab TáíwòAtelewoNovember 8, 2022November 8, 2022 by AtelewoNovember 8, 2022November 8, 2022022 Agbẹ́kẹ̀lé Ènìyàn Mo gbọ́ pé ayé wà Mo múra èrò ìjìnlẹ̀ Mo rí i pẹ́dàá ń ráyé lò Mo múra,... Read more
EwìOkùn Ìfẹ́ Yi! | Bákàrè Wahab TáíwòAtelewoNovember 8, 2022November 8, 2022 by AtelewoNovember 8, 2022November 8, 2022023 Okùn Ìfẹ́ Yi! Ìfẹ́ pọ́gbọ̀n, ó jọgbọ̀n Ìfẹ̀ pégba, ó jugba Ìfẹ́ pérínwó, ó jurínwó Ìfẹ́ẹ̀fẹ́ táyé fẹ́lá lóko Kò... Read more
EwìỌjà Layé àti Ewì Mìíràn | Olúwáfẹ́mi Kẹ́hìndé LawrenceAtelewoOctober 24, 2022October 24, 2022 by AtelewoOctober 24, 2022October 24, 2022029 ỌJÀ LAYÉ ỌJÀ LAYÉ Ọjà layé ọ̀rẹ́ mìi, Ọjà layé ará. Gbogbo ọmọ adáríhunrun pátá lówá nájà láyé, Dandan sì... Read more
Àpilẹ̀kọÌwádìíỌdún ọlọ́jọ́ | Olúwáfẹ́mi Ƙẹ́hìndé LawrenceAtelewoOctober 5, 2022October 12, 2022 by AtelewoOctober 5, 2022October 12, 20221126 Ọdún Ọlọ́jọ́ jẹ́ ọdún tó wuyì tó sì ṣe pàtàkì ní ilé-ifẹ̀, ọdọọdún ni wọ́n máa ń ṣe ọdún yìí.... Read more
Àpilẹ̀kọÀṣàyàn OlóòtúÌwádìíỌlọ́jọ́ ti dé | Dunni AdénúgàAtelewoOctober 5, 2022October 5, 2022 by AtelewoOctober 5, 2022October 5, 2022047 Mi ò rántí ìgbà tí mo kọ́kọ́ gbọ́ gbólóhùn “Ọlọ́jọ́” nínú ọ̀rọ̀, àmọ́ mo rántí wípé nígbà èwe mi, tí... Read more
Aáyan ògbufọ̀EwìÌjẹ́ Abiyamọ Ní Àríwá Àti Ewì Mìíràn | Ayọ̀bámi Káyọ̀déAtelewoOctober 9, 2021October 9, 2021 by AtelewoOctober 9, 2021October 9, 20210561 Ìjẹ́ Abiyamọ Ní Àríwá/ Being a mother in the north Ìjẹ́ abiyamọ ni àríwá Mo máa ń lo ìgbà mi... Read more
Àṣàyàn OlóòtúEwìÈèmọ̀ Ní Pópó Àti Ewì Mìíràn|Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀AtelewoOctober 9, 2021October 9, 2021 by AtelewoOctober 9, 2021October 9, 20210487 Èèmọ̀ Ní Pópó Ẹ wá wo ohun tí mo rí Ẹ dákun ẹ wá Ṣẹ̀ídà. Kàyéfì lohun tí mo rí... Read more
Àṣàyàn OlóòtúEwìỌ̀kànlélọ́gọ́ta Ọdún Nínú Ìyà | Mustapha SherifAtelewoOctober 1, 2021October 1, 2021 by AtelewoOctober 1, 2021October 1, 20210517 Àrà mí ò rírí, mo rórí Ológbò látẹ Ajá wẹ̀wù, ó rósọ, ó tún gbọ́mọ́ dáni Èké dáyé, áásà dàpòmú... Read more
Àṣàyàn OlóòtúEwìṢé Òmìnira Nì Yìí? | Bakare Wahab TaiwoAtelewoOctober 1, 2021October 1, 2021 by AtelewoOctober 1, 2021October 1, 20214 924 A fẹ́ á jẹ máà fẹ́ á yó, Tó ń fúnni lóko ìdí ọ̀pẹ ro. Mo gbédìí fórílẹ̀-èdè, Tó sọ̀yà... Read more