Àpilẹ̀kọ Àṣàyàn Olóòtú EwìÌbínú |Waliyullah Túndé Abímbọ́laatelewoSeptember 23, 2020September 23, 2020 by atelewoSeptember 23, 2020September 23, 20200405Ìbínú kò mọ̀ pé olówó òun ò lẹ́sẹ̀ ńlẹ̀. Ọ̀rẹ́ wa kan ló fi àṣejù kó bá ara rẹ̀ lẹ́nu...Read more
Àpilẹ̀kọ Àṣàyàn Olóòtú ÌtànẸ̀yìnlàárò | Ọládẹ̀jọ Hammed Ọ́atelewoAugust 31, 2020August 31, 2020 by atelewoAugust 31, 2020August 31, 20200645Àgbẹ̀ paraku ni Àkànó. Ìṣẹ́ àgbẹ̀ yí náà ni ó ń ṣe tí ó fi fẹ́ ìyàwó mérin tí ó...Read more
Àpilẹ̀kọ Àṣàyàn Olóòtú ÌtànKọ́kọ́rọ́ Ilé |Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀atelewoAugust 19, 2020August 19, 2020 by atelewoAugust 19, 2020August 19, 20200595 Ọjọ́ tí mo ti ń fi àwo òyìnbó jẹun kò fọ́ mọ́ mi lọ́wọ́ rí. Ohun tí ènìyàn kúkú...Read more
Àpilẹ̀kọ Àṣàyàn Olóòtú ÌtànKọ̀lọ̀rọ̀sí | Khadijah Ọlájùmọ̀kẹ́ Kọ́lápọ̀atelewoAugust 3, 2020August 3, 2020 by atelewoAugust 3, 2020August 3, 20200539Inú títa ló jí mi. Mo tilẹ̀ kọ́kọ́ rò pé àlá tí mo lá ni ó fà á ni –...Read more
Àpilẹ̀kọ Àṣàyàn OlóòtúẸni Ìjà Ò Bá |Gàníyù Saheed Ìṣọ̀láatelewoJuly 6, 2020July 6, 2020 by atelewoJuly 6, 2020July 6, 20200394Ọmọ bíbí ìlú Ifón ni Abíọ́dún; ó sì fẹ́ràn ìlú rẹ̀ púpọ̀. Ọkàn ò jọ̀kan ẹ̀bùn ni Olódùmarè fi jíǹkí ...Read more
Àpilẹ̀kọ Àṣàyàn Olóòtú EwìEwì ní ìrántí Adébáyọ̀ Fálétí, Akínwùmí Ìṣọ̀lá, àti Ọládẹ̀jọ Òkédìjí |Kọ́dáolú Tolúlọpẹ́atelewoJune 20, 2020June 23, 2020 by atelewoJune 20, 2020June 23, 20200335Apá Kiní Emọ́ kú ojú òpó dí Eésùn là, o là dànù Ọ̀pálánbá ọtí èèbó fọ́ Onígbá sọọ́ kò ri...Read more
Àpilẹ̀kọ Àṣàyàn Olóòtú EwìḰíkorò Ewúro àti Àwọn Ewì Méjì Míràn |Ìyanuolúwa AdénléatelewoMay 20, 2020May 20, 2020 by atelewoMay 20, 2020May 20, 20200443Kíkorò Ewúro Gbogbo ènìyàn ló mọ̀ pé Adùn ló yẹ kí ó gbẹ̀yìn ewúro Ṣùgbọ́n kò sẹ́ni tí ó ń...Read more
Àpilẹ̀kọ EwìAkéwì Àti Ewì Míràn | Ṣégun Ṣóẹ̀tánatelewoMay 20, 2020May 20, 2020 by atelewoMay 20, 2020May 20, 20200632Akéwì Èmi lakéwì, mo lóyin létè. Mo kẹ̀tẹ̀ǹfẹ̀ ìmọ̀ Mo le sọrọ́ dòótọ́ bí n bá fẹ́! Bó wù mí,...Read more
Àpilẹ̀kọ Ìtọ́wò Ìwé Àtẹ́lẹwọ́Ẹ̀rọ Ìránsọ | Kọ́lápọ̀ Ọlájùmọ̀kẹ́atelewoOctober 1, 2019October 4, 2019 by atelewoOctober 1, 2019October 4, 20190587Bàbá afọ́jú kan wà tí ó máa ń kọjá níwájú ilé wa nígbà tí mo wà ní kékeré. Ó dúdú...Read more
Àpilẹ̀kọ Ìtọ́wò Ìwé Àtẹ́lẹwọ́Lẹ́tà: Ọ̀rọ̀ Kẹ̀kẹ́ | ‘Gbénga AdéọbaatelewoOctober 1, 2019October 4, 2019 by atelewoOctober 1, 2019October 4, 20190635Ẹ forí jìn mí o, ẹ̀yin tí è ń gbé inú ilé yí. Ẹ̀rù ajá yín tí ó ń bà...Read more