Àṣàyàn Olóòtú EwìDèbórà, Obìnrin Ogun àti Ewì Mìíràn |Ìbùkúnolúwa DàdaatelewoMay 30, 2022May 30, 2022 by atelewoMay 30, 2022May 30, 20220118Dèbórà, Obìnrin Ogun Ìmísí: Ìwé nípa ìgbésí ayé Àyìnlá Ọmọ Wúrà Ìwé tó kọ nípa a rẹ̀ kìí ṣé mímọ́...Read more
Àṣàyàn Olóòtú EwìÈèmọ̀ Ní Pópó Àti Ewì Mìíràn|Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀AtelewoOctober 9, 2021October 9, 2021 by AtelewoOctober 9, 2021October 9, 20210353Èèmọ̀ Ní Pópó Ẹ wá wo ohun tí mo rí Ẹ dákun ẹ wá Ṣẹ̀ídà. Kàyéfì lohun tí mo rí...Read more
Àṣàyàn Olóòtú EwìỌ̀kànlélọ́gọ́ta Ọdún Nínú Ìyà | Mustapha SherifAtelewoOctober 1, 2021October 1, 2021 by AtelewoOctober 1, 2021October 1, 20210372Àrà mí ò rírí, mo rórí Ológbò látẹ Ajá wẹ̀wù, ó rósọ, ó tún gbọ́mọ́ dáni Èké dáyé, áásà dàpòmú...Read more
Àṣàyàn Olóòtú EwìṢé Òmìnira Nì Yìí? | Bakare Wahab TaiwoAtelewoOctober 1, 2021October 1, 2021 by AtelewoOctober 1, 2021October 1, 20214 570A fẹ́ á jẹ máà fẹ́ á yó, Tó ń fúnni lóko ìdí ọ̀pẹ ro. Mo gbédìí fórílẹ̀-èdè, Tó sọ̀yà...Read more
Aáyan ògbufọ̀ Àṣàyàn Olóòtú Rìfíù ÌwéÌrírí Òbí Àti Ìtọ́jú Ọmọ Nínú “Ìgbà Èwe” Láti Ọwọ́ Kọ́lá Túbọ̀sún | Rasaq Malik Gbọ́láhànAtelewoAugust 10, 2021August 11, 2021 by AtelewoAugust 10, 2021August 11, 20210488Àkọ́lé Ìwé: Ìgbà Èwe (Childhood)Ònkọ̀wé: Emily R. Grosholz Olùtúmọ̀ sí Èdè Yorùbá: Kọ́lá Túbọ̀sùnỌdún Tó Jáde: 2021Olùtẹ̀wé: Ouida BooksISBN: 978-978-990-701-4...Read more
Àṣàyàn Olóòtú ÀwòránKáràkátà Àti Àwóran míràn |Awósùsì OlúwábùkúnmiatelewoJuly 26, 2021August 11, 2021 by atelewoJuly 26, 2021August 11, 20210314Káràkátà Mo ya àwòrán yìí ní ọdún 2020 nígbàtí àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 gbòde kan. Ìyàlẹ́nu ló jẹ fún mí nígbà...Read more
Àṣàyàn Olóòtú EwìWèrè Alásọ àti Àwọn Ewì Míràn |Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀atelewoJuly 26, 2021August 11, 2021 by atelewoJuly 26, 2021August 11, 20210471Ta Ni Kí Ń Bi? Mo wò òréré ayé yíká Ayé ò yé mí rárá Mo wò sánmọ̀ lọ súà...Read more
Àpilẹ̀kọ Àṣàyàn OlóòtúLálẹ́ Ìgbéyàwó | Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀atelewoJuly 26, 2021August 11, 2021 by atelewoJuly 26, 2021August 11, 20210399Bí aré kò bá tó aré a kì í pòwe, bí ọ̀rọ̀ kò bá tọ́rọ̀ a kìí fìtàn balẹ̀, bí...Read more
Aáyan ògbufọ̀ Àṣàyàn Olóòtú EwìWíwá Ilé L’ájò |Adépọ̀jù Isaiah GbéngaatelewoMarch 19, 2021March 22, 2021 by atelewoMarch 19, 2021March 22, 20210687Ọ̀nà tí ó yá jù láti dá'ná sun ara ẹni Ni nípa fifi iná sí ilé ẹni. Òlùkọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì...Read more
Àpilẹ̀kọ Àṣàyàn OlóòtúÌkòríta Mẹ́ta |Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀AtelewoMarch 19, 2021March 22, 2021 by AtelewoMarch 19, 2021March 22, 20211971Ìlẹ̀kẹ̀ má jà á sílé má jà á síta ibì kan ni yóò já sí lọ́jọ́ kan. Dùnúnkẹ́ rẹwà lọmọ....Read more