Agbẹ́kẹ̀lé Ènìyàn Mo gbọ́ pé ayé wà Mo múra èrò ìjìnlẹ̀ Mo rí i pẹ́dàá ń ráyé lò Mo múra, ó di dúnníyàn Mo wá…
Okùn Ìfẹ́ Yi! Ìfẹ́ pọ́gbọ̀n, ó jọgbọ̀n Ìfẹ̀ pégba, ó jugba Ìfẹ́ pérínwó, ó jurínwó Ìfẹ́ẹ̀fẹ́ táyé fẹ́lá lóko Kò ju kí wọ́n ríhun filá…
ỌJÀ LAYÉ ỌJÀ LAYÉ Ọjà layé ọ̀rẹ́ mìi, Ọjà layé ará. Gbogbo ọmọ adáríhunrun pátá lówá nájà láyé, Dandan sì ni ká padà s'ílé e…
Ìdùnnú a ṣubú lu ayọ̀ Lọ́jọ́ a bá bímọ tuntun sáyé Tẹbítará a kí túńfúlù káàbọ̀. Bọ́jọ́ ṣe ń gorí ọjọ́ Tóṣù ń gorí oṣù…
Dèbórà, Obìnrin Ogun Ìmísí: Ìwé nípa ìgbésí ayé Àyìnlá Ọmọ Wúrà Ìwé tó kọ nípa a rẹ̀ kìí ṣé mímọ́ Bíkòṣe ti mímọ̀— Ìmọ̀ ogun.…
Ìjẹ́ Abiyamọ Ní Àríwá/ Being a mother in the north Ìjẹ́ abiyamọ ni àríwá Mo máa ń lo ìgbà mi láti há Orúkọ àwọn ọmọdékùnrin…
Èèmọ̀ Ní Pópó Ẹ wá wo ohun tí mo rí Ẹ dákun ẹ wá Ṣẹ̀ídà. Kàyéfì lohun tí mo rí A gbọ́ sọgbá nù A…
Àrà mí ò rírí, mo rórí Ológbò látẹ Ajá wẹ̀wù, ó rósọ, ó tún gbọ́mọ́ dáni Èké dáyé, áásà dàpòmú Huuuuun kò jọmílójú Torí mo…
A fẹ́ á jẹ máà fẹ́ á yó, Tó ń fúnni lóko ìdí ọ̀pẹ ro. Mo gbédìí fórílẹ̀-èdè, Tó sọ̀yà dohun àjẹsùn fáráàlú. Wọ́n fẹ́…
Ta Ni Kí Ń Bi? Mo wò òréré ayé yíká Ayé ò yé mí rárá Mo wò sánmọ̀ lọ súà Kò yé mi bó ṣe…