
ÀTẸ́LẸWỌ́ ṣe àgbékalẹ̀ Ayẹyẹ Àyájọ́ Ọjọ́ Èdè Abínibí Pẹ̀lú Ayẹyẹ Ọjọ́ Ẹ̀bùn fún Ìdíje Ìwé Kíkọ Ti Ọdún 2022
Àkòrí: Èdè Ọmọ ni Ìjánu Ọmọ
Gbàgede Ètò: BNI Youth Centre, First Floor, U&I Building, University of Ibadan àti lóri Facebook Wa.
Ọjọ́: Ọjọ́ kejìdínlógún, Oṣù Kejì Ọdún 2022
Ẹ lè darapọ̀ mọ́ wa lóri afẹ́fẹ́ (Zoom) pẹ̀lú linkì yìí. Tàbí
Meeting ID: 886 0772 7252
Passcode: yoruba
For Àtìlẹyìn àti ìwádìí, ẹ kàn sí 07061282516, 08169864345.

International Mother Language Day
ÀTẸ́LẸWỌ́ presents International Mother Language Day Celebration featuring
- ÀTẸ́LẸWỌ́ PRIZE FOR YORÙBÁ LITERATURE 2022 AWARD CEREMONY
- Phase 2 Launching of Ògbóntarigì Documentary Project
Theme: Èdè Ọmọ ni Ìjánu Ọmọ
Venue: BNI Youth Centre, First Floor, U&I Building, University of Ibadan and Facebook Live
Date: February 18, 2022
Those who are not able to join physically can register to join the event on Zoom. or
Meeting ID: 886 0772 7252
Passcode: yoruba
For Support & Partnership, call 07061282516, 08169864345.