Àṣàyàn OlóòtúEwìDèbórà, Obìnrin Ogun àti Ewì Mìíràn |Ìbùkúnolúwa DàdaatelewoMay 30, 2022May 30, 2022 by atelewoMay 30, 2022May 30, 20220224 Dèbórà, Obìnrin Ogun Ìmísí: Ìwé nípa ìgbésí ayé Àyìnlá Ọmọ Wúrà Ìwé tó kọ nípa a rẹ̀ kìí ṣé mímọ́... Read more
Aáyan ògbufọ̀Àṣàyàn OlóòtúRìfíù ÌwéÌrírí Òbí Àti Ìtọ́jú Ọmọ Nínú “Ìgbà Èwe” Láti Ọwọ́ Kọ́lá Túbọ̀sún | Rasaq Malik Gbọ́láhànAtelewoAugust 10, 2021August 11, 2021 by AtelewoAugust 10, 2021August 11, 20210591 Àkọ́lé Ìwé: Ìgbà Èwe (Childhood)Ònkọ̀wé: Emily R. Grosholz Olùtúmọ̀ sí Èdè Yorùbá: Kọ́lá Túbọ̀sùnỌdún Tó Jáde: 2021Olùtẹ̀wé: Ouida BooksISBN: 978-978-990-701-4... Read more
Àṣàyàn OlóòtúÀwòránKáràkátà Àti Àwóran míràn |Awósùsì OlúwábùkúnmiatelewoJuly 26, 2021August 11, 2021 by atelewoJuly 26, 2021August 11, 20210373 Káràkátà Mo ya àwòrán yìí ní ọdún 2020 nígbàtí àjàkálẹ̀ àrùn Covid-19 gbòde kan. Ìyàlẹ́nu ló jẹ fún mí nígbà... Read more
Àṣàyàn OlóòtúEwìWèrè Alásọ àti Àwọn Ewì Míràn |Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀atelewoJuly 26, 2021August 11, 2021 by atelewoJuly 26, 2021August 11, 20210623 Ta Ni Kí Ń Bi? Mo wò òréré ayé yíká Ayé ò yé mí rárá Mo wò sánmọ̀ lọ súà... Read more
Àpilẹ̀kọÀṣàyàn OlóòtúLálẹ́ Ìgbéyàwó | Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀atelewoJuly 26, 2021August 11, 2021 by atelewoJuly 26, 2021August 11, 20210492 Bí aré kò bá tó aré a kì í pòwe, bí ọ̀rọ̀ kò bá tọ́rọ̀ a kìí fìtàn balẹ̀, bí... Read more
Àpilẹ̀kọInúlayéwà Ọkọ Mọ́mbé | Lánasẹ̀ HusseinatelewoJuly 26, 2021August 11, 2021 by atelewoJuly 26, 2021August 11, 20211478 Kò sí ẹnì kankan tí kò mọ Ìyá àgbà ní abàá Alẹ́mọ́, kìí sọ ìtàn kan ní ẹ̀ẹ̀mejì. Àgbà òpìtàn... Read more
Aáyan ògbufọ̀Àṣàyàn OlóòtúEwìWíwá Ilé L’ájò |Adépọ̀jù Isaiah GbéngaatelewoMarch 19, 2021March 22, 2021 by atelewoMarch 19, 2021March 22, 20210741 Ọ̀nà tí ó yá jù láti dá'ná sun ara ẹni Ni nípa fifi iná sí ilé ẹni. Òlùkọ́ èdè Gẹ̀ẹ́sì... Read more
Àpilẹ̀kọÀṣàyàn OlóòtúÌkòríta Mẹ́ta |Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀AtelewoMarch 19, 2021March 22, 2021 by AtelewoMarch 19, 2021March 22, 202111131 Ìlẹ̀kẹ̀ má jà á sílé má jà á síta ibì kan ni yóò já sí lọ́jọ́ kan. Dùnúnkẹ́ rẹwà lọmọ.... Read more
Àṣàyàn OlóòtúEwìB’ọ́bẹ̀ ẹ bá dùn àti ewì míràn | Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀AtelewoMarch 19, 2021March 22, 2021 by AtelewoMarch 19, 2021March 22, 20210649 Olú ti d'ẹ́nu ní ìbúǹbú Ó di dandan kó jẹun. Ebi kìí wọnú kọ́rọ̀ míì ó wọ̀ ọ́ Òrìṣà bí ọ̀fun ò sí... Read more
Àṣàyàn OlóòtúEwìMàkàn Màkàn àti Àpọ́n |Ọlátúndé ÀyìnláatelewoMarch 19, 2021March 22, 2021 by atelewoMarch 19, 2021March 22, 20210696 Olóko ń sun kún Oní igba ewùrà ló nù ní ódẹ̀ òhun Ará ilé mi ní: òhun ò l'oko, bẹ́ẹ̀... Read more