ỌMỌ ÒRUKÀN Ikọ́ wíwú ológìnní kìí ṣàfiṣe Ìran baba wọn níí wúkọ́ fee. Gbígbó ajá kì í kúkú pajá. Ìran wọn ló ní gbígbó. A…
Ẹ̀rù àwọn ará ibí bà mí jọjọ. Ẹrù àìbìkítà wọn a máa ṣe mí bí ọyẹ́ ti ń ṣe ọmọ ìkókó. À ṣé ọdẹ tí…
Ṣóo wo iwájú tóò r’ẹ́nìkan O w’ẹ̀yìn wò, óò r’éèyàn L’ọ́tùn-ún l’ósì, ilẹ̀ tẹ́ lọ bẹẹrẹ Àṣẹ̀yìnwá àṣẹ̀yìnbọ̀, o ní ikú ló kàn Ọjọ́ a…
Orin: Ẹnikẹ́ni tí ìwọ bá nípa láti se ìrànlọ́wọ́ fún Òun náà lẹni kejì rẹ, tọ́jú rẹ. Ẹnikẹ́ni tó bá nípa láti ṣe ìrànwọ́ fún…
Ọ̀rọ̀ kan tí ń dùn mi lọ́kàn ọjọ́ pẹ́. Àsìkò tí tó wàyí tí n ó rò fáráalé. Ọ̀rọ̀ kan tí ń ṣe mí ní…
Aáyan ògbufọ̀ iṣẹ́ “Àbíkú” láti ọwọ́ Wọlé Ṣóyínká Asán, òfúútù fẹ́ẹ̀tẹ̀, aásà tí kò ní kán-ún ni gbogbo ìlẹ̀kẹ̀ tí ẹ fi dèmí m'áyé Èmi…
Kò sẹ́ranko bí kìnnìún níjù. Bó dolókìtì ẹni tí ó ṣe bí ọ̀bọ ò sí. Ẹranko tí ó sọ pé kí ìkookò ó dákẹ́ Wọ́n…
Ẹnìkan Ò Layé Ẹni ayé ńṣe maràba fún ó sọ́ra fẹ́nu aráyé Ẹ wí fún gbogbo molegòkè-molesọ̀ pé mo ní kí wọ́n rọra Gbogbo ẹni…
Ọmọ mí Mo bá wọn ná'jà Akẹ̀ẹ̀sán Mo bá wọn pé lọ́jà Orísúnbáre Ohun mò ń wá di tíntín abẹ́rẹ́ tó sọnù Mo wẹ'dò mẹ́fà,…
Ẹ Bọ̀wọ̀ F’ágbà “Ajá tó r’ólówó ẹ̀ rojú, kín ní ó f’ólówó è se kò tié yé mi.” —Éégunmọgají Àyìnlá Ọmọwúrà. Ìrírí kí lọmọdé ní,…