EwìBí a bá sọ̀kò lọ́jà … | Malik AdéníyìatelewoSeptember 23, 2020September 23, 2020 by atelewoSeptember 23, 2020September 23, 20200616Orin: Ẹnikẹ́ni tí ìwọ bá nípa láti se ìrànlọ́wọ́ fún Òun náà lẹni kejì rẹ, tọ́jú rẹ. Ẹnikẹ́ni tó bá...Read more
EwìẸni Àpọ́nlé L’abo|Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀atelewoAugust 31, 2020August 31, 2020 by atelewoAugust 31, 2020August 31, 20200874Ọ̀rọ̀ kan tí ń dùn mi lọ́kàn ọjọ́ pẹ́. Àsìkò tí tó wàyí tí n ó rò fáráalé. Ọ̀rọ̀ kan...Read more
Aáyan ògbufọ̀ EwìÀbíkú | Sùmọ́nù Ajíbọ́lá Adéjùmọ̀atelewoAugust 19, 2020August 19, 2020 by atelewoAugust 19, 2020August 19, 20200498Aáyan ògbufọ̀ iṣẹ́ “Àbíkú” láti ọwọ́ Wọlé Ṣóyínká Asán, òfúútù fẹ́ẹ̀tẹ̀, aásà tí kò ní kán-ún ni gbogbo ìlẹ̀kẹ̀ tí...Read more
Àṣàyàn Olóòtú EwìKò Jọra Wọn |Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀atelewoAugust 3, 2020August 3, 2020 by atelewoAugust 3, 2020August 3, 20200597Kò sẹ́ranko bí kìnnìún níjù. Bó dolókìtì ẹni tí ó ṣe bí ọ̀bọ ò sí. Ẹranko tí ó sọ pé...Read more
Àpilẹ̀kọ Àṣàyàn Olóòtú EwìEwì ní ìrántí Adébáyọ̀ Fálétí, Akínwùmí Ìṣọ̀lá, àti Ọládẹ̀jọ Òkédìjí |Kọ́dáolú Tolúlọpẹ́atelewoJune 20, 2020June 23, 2020 by atelewoJune 20, 2020June 23, 20200373Apá Kiní Emọ́ kú ojú òpó dí Eésùn là, o là dànù Ọ̀pálánbá ọtí èèbó fọ́ Onígbá sọọ́ kò ri...Read more
Àpilẹ̀kọ Àṣàyàn Olóòtú EwìḰíkorò Ewúro àti Àwọn Ewì Méjì Míràn |Ìyanuolúwa AdénléatelewoMay 20, 2020May 20, 2020 by atelewoMay 20, 2020May 20, 20200495Kíkorò Ewúro Gbogbo ènìyàn ló mọ̀ pé Adùn ló yẹ kí ó gbẹ̀yìn ewúro Ṣùgbọ́n kò sẹ́ni tí ó ń...Read more
Àpilẹ̀kọ EwìAkéwì Àti Ewì Míràn | Ṣégun Ṣóẹ̀tánatelewoMay 20, 2020May 20, 2020 by atelewoMay 20, 2020May 20, 20200698Akéwì Èmi lakéwì, mo lóyin létè. Mo kẹ̀tẹ̀ǹfẹ̀ ìmọ̀ Mo le sọrọ́ dòótọ́ bí n bá fẹ́! Bó wù mí,...Read more
Ewì Ìtọ́wò Ìwé Àtẹ́lẹwọ́Ojúlarí | Rasaq Malik Gbọ́láhànatelewoOctober 1, 2019October 4, 2019 by atelewoOctober 1, 2019October 4, 20190674Moti dé'lé ayé ọjọ́ ti pẹ́, Moti d'ókè eèpẹ̀ ọ̀nà ti jì, Ṣebí ojúlarí ọ̀rẹ́ ò dénú. Ṣààsà ènìyàn ní...Read more
Ewì Ìtọ́wò Ìwé Àtẹ́lẹwọ́Nítàn kí o tó tán | Malik AdéníyìatelewoOctober 1, 2019October 4, 2019 by atelewoOctober 1, 2019October 4, 20190557Gbogbo ohun tí a bá ṣe lónìí, ọ̀rọ̀ ìtàn ni bó dọ̀la Gbogbo ayé ló máa tán Gbogbo wa la...Read more
Àpilẹ̀kọ EwìẸ̀rọ Omi àti Ẹ̀rù | Mof’Ólúwawò O MojọláOlúwaatelewoDecember 2, 2018December 2, 2018 by atelewoDecember 2, 2018December 2, 20182 636Ẹ̀rọ Omi Báwo ni ó máa ń rí l’ára nígbà tí o bá ń gbìyànjú àti gba ẹlòmíràn là tí...Read more