Àṣàyàn Olóòtú EwìKí Akọni Tó Di Akọni | Akínrìnádé Fúnminíyì IsaacatelewoJuly 25, 2020July 25, 2020 by atelewoJuly 25, 2020July 25, 20200466Mo lé téńté sórí igi odán mobojú wolẹ̀ láti wo àwọn ẹ̀dá tí Elédùmarè dá sílé Ayé À'teku, à'teye, àti...Read more
EwìẸ Bọ̀wọ̀ F’ágbà Àti Ewì Míràn|Àrásí Kamaldeen Moyọ̀sọ́rẹatelewoJuly 6, 2020July 8, 2020 by atelewoJuly 6, 2020July 8, 20200343Ẹ Bọ̀wọ̀ F’ágbà “Ajá tó r’ólówó ẹ̀ rojú, kín ní ó f’ólówó è se kò tié yé mi.” —Éégunmọgají Àyìnlá...Read more
Àpilẹ̀kọ Àṣàyàn OlóòtúẸni Ìjà Ò Bá |Gàníyù Saheed Ìṣọ̀láatelewoJuly 6, 2020July 6, 2020 by atelewoJuly 6, 2020July 6, 20200417Ọmọ bíbí ìlú Ifón ni Abíọ́dún; ó sì fẹ́ràn ìlú rẹ̀ púpọ̀. Ọkàn ò jọ̀kan ẹ̀bùn ni Olódùmarè fi jíǹkí ...Read more
Àṣàyàn Olóòtú EwìCoro ló pojú kòró jẹ àti ewì míràn|Huswat LawalatelewoJune 23, 2020June 23, 2020 by atelewoJune 23, 2020June 23, 20200447Coro ló pojú kòró jẹ Ṣebí láti ọjọ́ táláyé ti dáyé L'ayé tí ń yí, tí ọmọ adáríhunrun ti ń...Read more
Àpilẹ̀kọ Àṣàyàn Olóòtú EwìEwì ní ìrántí Adébáyọ̀ Fálétí, Akínwùmí Ìṣọ̀lá, àti Ọládẹ̀jọ Òkédìjí |Kọ́dáolú Tolúlọpẹ́atelewoJune 20, 2020June 23, 2020 by atelewoJune 20, 2020June 23, 20200375Apá Kiní Emọ́ kú ojú òpó dí Eésùn là, o là dànù Ọ̀pálánbá ọtí èèbó fọ́ Onígbá sọọ́ kò ri...Read more
EwìEgbìrìn | Salawu ỌlájídéatelewoJune 3, 2020June 3, 2020 by atelewoJune 3, 2020June 3, 20200463Egbìrìn ọ̀tẹ̀ bí à ń ṣé pa ìkan ni ọ̀kan rú ní ìlú mi. Ní àgbàlá òdòdó yìí ẹ̀gún ń...Read more
EwìOrí | Akínyẹmí Muhammed AdédèjìatelewoJune 3, 2020June 3, 2020 by atelewoJune 3, 2020June 3, 20200587Orí l'atọ́kùn ara, Olóòótọ́ tí ń darí ìwà, Awakọ̀ ti kii sìnà l'ójú 'gbó, Orí mi gbé mi dé bi...Read more
Àṣàyàn Olóòtú EwìÀ-pè-kánukò àti ewì mìrán | Táófíkì AyéyẹmíatelewoJune 3, 2020June 3, 2020 by atelewoJune 3, 2020June 3, 20200333À-pè-kánukò Àpèkánukò! Àpèṣ'ẹnu ṣùùtì Bí-i músù ú rẹ́ja nínú ike. Owó ní í jẹ́bẹ̀, ìwọ ọ̀rẹ́, Bí kò bá sí...Read more
Àpilẹ̀kọ Àṣàyàn Olóòtú EwìḰíkorò Ewúro àti Àwọn Ewì Méjì Míràn |Ìyanuolúwa AdénléatelewoMay 20, 2020May 20, 2020 by atelewoMay 20, 2020May 20, 20200496Kíkorò Ewúro Gbogbo ènìyàn ló mọ̀ pé Adùn ló yẹ kí ó gbẹ̀yìn ewúro Ṣùgbọ́n kò sẹ́ni tí ó ń...Read more
Àpilẹ̀kọ EwìAkéwì Àti Ewì Míràn | Ṣégun Ṣóẹ̀tánatelewoMay 20, 2020May 20, 2020 by atelewoMay 20, 2020May 20, 20200700Akéwì Èmi lakéwì, mo lóyin létè. Mo kẹ̀tẹ̀ǹfẹ̀ ìmọ̀ Mo le sọrọ́ dòótọ́ bí n bá fẹ́! Bó wù mí,...Read more