Ìkòríta Mẹ́ta |Sheriffdeen Adéọlá Ògúndípẹ̀
Ìlẹ̀kẹ̀ má jà á sílé má jà á síta ibì kan ni yóò já sí...
Jẹ́ àpèrè tó ń m’ójútó ìgbéga èdè àti àṣà Yorùbá. Onírurú ọ̀nà la fí ń ṣe èyí. Nípa ṣiṣe àtẹ̀jáde ìwé lítíresọ̀ orí afẹ́fẹ́, ṣíṣe ètò ẹgbẹ́ òǹkàwé, igbékalẹ̀ ẹ̀kọ́ èdè tó yanrantí, ṣíṣe aáyan ògbufọ̀ àti títa oríṣiríṣi ìwé lítíréṣọ̀ Yorùbá. Ẹ ṣe ìwádí sí wájú si nípa títẹ àwòrán ìsàlẹ̀ yìí.