ÀKỌ́LÉ :Orí OHUN ÈLÒ: Ọ̀dà Ọìlì ỌDÚN : 2014/2015 ORÚKỌ AYÀWÒRÁN: Ọláòníye Àllíù Fèyíṣọlá GBÓLÓHÙN IṢẸ́ NÁÀ– Òrìṣà pàtàkì ni a mọ orí sí láàrín ọkanlélúgba irúnmọlẹ̀,…
Èyí ni ìtàn àròkọ kúkurú láti ẹnu Rasaq Malik Gbọ́lahàn. Bí ẹ̀yin naa fẹ wà ni àpèrè wa, ẹ kàn sí wa pẹ̀lú iṣẹ́ yin…
ÀKỌ́LÉ :onílù OHUN ÈLÒ: Ọ̀dà àkìrẹ́líkì ỌDÚN : 2018 ORÚKỌ AYÀWÒRÁN: Ọláòníye Àllíù Fèyíṣọlá SÍTÁILÌ: Araism (iṣẹ́ ọnà). ÀKỌ́LÉ :Agbè Ẹmu OHUN ÈLÒ : Òwú sílíkì.…
Ènìyàn Ènìyàn o, Ènìyàn yán Ènìyàn a b’ìdí yàn àn yán o Ènìyàn Òṣèlú, Ènìyàn ọ̀jẹ̀lú Ènìyàn tí ń f’agbáda gba agbada alágbẹ̀dẹ Ènìyàn tí…
Rasaq Malik jẹ́ akẹ́ẹ̀kọ́ gboyè nínú ìmọ̀ èdè gẹ̀ẹ́sì ní Ilé Ìwé gíga fásitì èyí tí o fì’dí ka’lẹ̀ sí ìlú Ìbàdàn. O jẹ́…