ÀTẸ́LẸWỌ́ did this project to celebrate Bàbá Láwuyì Ògúnníran, the famous author of Eégún Aláré and many other Yorùbá literature books. We also did this…
Àgbà ọ̀pàpà paradà owó ará ìlú paradà ó dọbẹ̀ níkùn àgbà àgbà òṣèlú, àgbà ọ̀jẹ̀lú wọn jẹ̀lú jẹ̀lú, ìlú wó wọn jẹ̀lú jẹ̀lú, ìlú lu.…
Jòjòló akéwì tún dé Mo fẹ́ kọrin ewì sétí aráyé Ẹ yá mi létí yín. Ọ̀rọ̀ fẹ́ máa jábọ́ bí odi ẹyìn. Kí ẹ sáré…
Ìbínú kò mọ̀ pé olówó òun ò lẹ́sẹ̀ ńlẹ̀. Ọ̀rẹ́ wa kan ló fi àṣejù kó bá ara rẹ̀ lẹ́nu ọjọ́ mẹ́ta yìí. Ó ń…
Eerin wó, Àjànàkú sùn bí òkè! O ṣe ni láàánú gidigidi láti gbọ́ pé Bàbá Láwuyì Ògúnníran, ọ̀kan gbòógí nínú àwọn òǹkọ̀we Yorùbá pa ‘po…
Àgbẹ̀ paraku ni Àkànó. Ìṣẹ́ àgbẹ̀ yí náà ni ó ń ṣe tí ó fi fẹ́ ìyàwó mérin tí ó wà ní ilé rẹ̀. Ohun…
Ọjọ́ tí mo ti ń fi àwo òyìnbó jẹun kò fọ́ mọ́ mi lọ́wọ́ rí. Ohun tí ènìyàn kúkú ń ṣe nìyí náà ní…
Inú títa ló jí mi. Mo tilẹ̀ kọ́kọ́ rò pé àlá tí mo lá ni ó fà á ni – èèyàn ò gbọdọ̀ jẹ ata…
Kò sẹ́ranko bí kìnnìún níjù. Bó dolókìtì ẹni tí ó ṣe bí ọ̀bọ ò sí. Ẹranko tí ó sọ pé kí ìkookò ó dákẹ́ Wọ́n…
Ẹnìkan Ò Layé Ẹni ayé ńṣe maràba fún ó sọ́ra fẹ́nu aráyé Ẹ wí fún gbogbo molegòkè-molesọ̀ pé mo ní kí wọ́n rọra Gbogbo ẹni…